Followers

"Hymn of Mercy" - Oluwalonibisi - Lyrics









Key GM

Je kaanu de be fun mi
Nibi to ju mi ode, 
nibi to un mi ode
Je kaanu de be Funmi 

Je kaanu wa solution
Ni bi taye Sope opin
Ton ti ni ko sona mo
Je kaanu wa solution

Je kaanu Dami lare 
Nigba ti dajo fohun 
Tati dami lebi o
Je kaanu Damilare

Je kaanu saanu Funmi
Ni bi ti oti Sunmi
Ni bi ti ranwo o si 
Je kaanu saanu funmi 

Nibi toju mi ode 
Nibi toun mi ode
Je kaanu debe funmi

Nibi taye Sope opin
Ton ti ni ko sona mo
Je kaanu wa solution

Nigba ti dajo foun
Tati damilebi o
Je kaanu damilare 

Nibi ti oti sun mi
Nibi ti ranwo o si
Je kaanu saanu funmi 

Je kaanu de be fun mi
Nibi to ju mi ode, 
nibi to un mi ode
Je kaanu de be Funmi

Comments

Popular posts from this blog

"Niwaju Oba" - Pelumi Deborah - tonic solfa & lyrics

"Yahweh Sabaoth" - Nathaniel Bassey - lyrics and tonic solfa

"Awamaridi" (Unsearchable God) by Douye Ajeh feat. Todd Dulaney - Lyrics - Parts - Tonic Solfa