Followers

"Ipe (The Calling)" - Lyrics - Adeyinka Alaseyori Feat. BBO

Key BM















Chorus:
Ipe to pe mi
Okan fi saanu mu ni 
Ero po o tole lo

Moran ti story meta ninu bibeli
Emeta ni peteru se Jesu 
Ose lalakoko, ose lele Keji ateleketa
Sugbon iwe Mimo je o mayemi pe peteru kan na yi
That this same Peter healed many with his shadow
Peteru tose Jesu lemeta 
E gbo Iru ipe tope peteru so to si, ko tosi 
Thats number one
Moran ti story Saul to so di Paul 
Awon onigbagbo ni Saul manwakiri
Ipetope saulu yi o, aanu ni 
Eni elekata Oni mose 
Oro oraodaa lenu mose akololo ni mose
Baami pe Oni mose Iwo loma ko awon Eyan mi kuro Nile egypti
Oni Oluwa Oluwa wa Olorun awon omo Ogun
Se Iru Eni niwon so, Oro o da lenu mi oko mi

Aanu ni (2x)
Orin tin monko Egbe | aanu ni
Voice to fun mi yi o | aanu ni
Ebun to fi Demi lade | aanu ni
Talenti to fun mi | aanu ni
Oro ori mi | aanu ni
Ani Ebun to funmi se | aanu ni
Eni ton ranso to fun lebun yi o | aanu ni
Eni ton foso to fun ni strength | aanu ni
Designer to fun ni ogbon imo ati Oye nko | aanu ni
Alaseyori ki logbe yin debi | aanu ni
Content creator ni gbo ro
Oun tanje | aanu ni
Onranso feyan

Many are called few are chosen\2x
Im glad Im part of those you chosen

Ipe to pe mi…..

Tan ban fo iya sa sita bi aso 
Ai moye awon Eni tomaji telomiran kan
Dupe tie kin dupe temi, lototo lope wa
Awon oun tofe dupe fun to ba sa sita awon kan aji ka
Wanigbatemi toba ro pe ele yi le koko
Iwo to rope da nibo lowa
Ranso ranso, soro soro, korin korin, fere loun fun, ata jere Oja 
Gbowo yen soke, to fi Kole, to fi boko, ton fi bo aya, 

Ipe to gbe mi…,

Eni ton rorin ko 
Bosen Lu lonsen du
On lo layo oun bo layo
Sisun jiji ko
Lilo bibo nko
Orin nile Onfo loke
On ko aye gbo ti e
Ogbon imo Oye nko
Tofin layo ehn ehn
Oru layo, oso layo
Owo hospitu Ojade layo
Osun oji nko se

Oun tonpe ni aanu nipe
Kadani waye wo e susu kowa fun e ni oun totosi 
It means that what you don’t deserve
Wipe tin ba sa ipa, Gbogbo ogbo mi
Ati ogbon ati Oye Gbogbo Tofunmi
Bi ki Eyan boju weyin ko wo story mi, ibi tonti mumi bo Olorun mi
Pupo ninu awa tonlo kin sepe ase awon mistake kan ni time kan ri Olorun mi
Ase awon asise kan tojepe, Tolorun ban mu ru awon to felo ko je ko mu ru awa
Wipe ipe to pe mi, Emi gan fun ra mi mo pe mi o tosi
 
Aanu ni (2x)
Lilo bibo o
Olomi fun ogo re o
Pe Iru mi to pe o
Pe odororo lemi Lori 
Pe asiri mi bo
Awon kan wan womi bi mentor
Kin na wo Lara mi gan
Bi o se wo ton ri Lara mi o
Aanu lofi ponmi 
Aanu lofi package mi o

Ipe to pemi……

Se koseyin ni Kayefi, pe wundia ni Maria o
obi olugbala araye si bu je eran 
Aimoye olugbala laarin wa,fun dile tati jade wa, Iwo lolugbLa larin won, Ade bi o si bi Ke kere
Igbati olugbala de, oso o dolugbala fun won
Olugbala Iran kan loje, jajo dupe ipe yi o

Ipe to pe mi….

Ero po o tole lo o……

Comments

Popular posts from this blog

"Mo Moore" - Lyrics - Adeyinka Alaseyori

"Oshimiri Atata" (Tonic Solfa and Lyrics) - Faith Captain

"Earthen Vessel" (Tonic Solfa & Lyrics) - Theophilus Sunday