"Hymn of Mercy" - Oluwalonibisi - Lyrics
Key GM Je kaanu de be fun mi Nibi to ju mi ode, nibi to un mi ode Je kaanu de be Funmi Je kaanu wa solution Ni bi taye Sope opin Ton ti ni ko sona mo Je kaanu wa solution Je kaanu Dami lare Nigba ti dajo fohun Tati dami lebi o Je kaanu Damilare Je kaanu saanu Funmi Ni bi ti oti Sunmi Ni bi ti ranwo o si Je kaanu saanu funmi Nibi toju mi ode Nibi toun mi ode Je kaanu debe funmi Nibi taye Sope opin Ton ti ni ko sona mo Je kaanu wa solution Nigba ti dajo foun Tati damilebi o Je kaanu damilare Nibi ti oti sun mi Nibi ti ranwo o si Je kaanu saanu funmi Je kaanu de be fun mi Nibi to ju mi ode, nibi to un mi ode Je kaanu de be Funmi